
Gbajugbaja Olorin ati Oludari Labe Asia YBNL ti a mọ si BBanks gbe orin titun jade eyi ti o pe akọle rẹ ni Self Knowledge (SK), eyi ti O ba Ọmọ Egbe Rẹ Temmie Ovwasa ẹyi ti a mọ si YBNL Princess
#OrinTitun: Harrysong – Journey (Irin Ajo)
Sunday Bankole (BBanks) gbe orin titun naa jade, eyi ti o so nipa ireti ati igbagbo.
Ẹ gbọ Orin naa Ki e Jẹki A mọ Bi E ti fẹran rẹ to.