Skip to content

#OrinTitun: ADEKUNLE GOLD (@adekunleGold) Ft. PHEELZ – IRE (remix)

ADEKUNLE GOLD Ft. PHEELZ – IRE (remix)

Lẹyin ti orin “IRE” ti lọ kaakakiri agbanla aye, Adekunle Gold ati ọrẹ rẹ ti o jẹ ẹni ti o maa n po gbogbo eroja orin mọ ara wọn ti wọn yoo fi da ẹyọkan; iyẹn PHEELZ gbe remix orin naa jade ti awọn onijo si jo si orin naa ninu fidio naa.

Ẹ wo fidio naa ni ‘salẹ: