Skip to content

Ooni Wo Igbale fun Ayeye Olojo Festival

Awon ara ilu ile ife n retia won ajoji ti won ma wow a si ilu won fun ayeye olojo festival ti odun yii ti o ma waye ni Saturday to n bo.

Ooni ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, so eleyi di mimo ni irole ojo Sunday ni  ile ife kete ki o to wo  igbale fun asiko ojo meje (7 days) fun ipalemo fun ayeye.  Oba Ogunwusi se alaye siwaju si wipe olojo festival da lori sise ajoyo isese ojo akoko ti olorun da.

Leyin Ojo Meje yi ni won n reti ki Ooni jade kuro ni hahamo ti o wa ti o si ma wo ade AARe ti o ma n wo leekan lodun…

E TUN LE KA: Emi Ati Ooni Ko Fe Ara Wa Mo – Olori Wuraola

Oba Ogunwusi so wipe,  “Our ancestors will be appeased during the period and by the time I come out on Saturday for the grand finale, the seclusion rites would have been be concluded. It is a celebration of the creation of the universe and many visitors from within the country and the Diaspora will come around to celebrate with us. My duty is specifically to offer prayers and that I will do to the best of my ability. This year’s Olojo Festival will witness an unprecedented participation of foreigners; the members of the Black Caucus of the Pennsylvania House of Representatives and about 150 other black Americans have already indicated interest to participate in the festival.”

Oba ke pea won oniroyin pe ki won tubo maa se agbateru fun ikede to se anfaani fun olojo festival ati awon festivals Yoruba to ku.