Skip to content

Ominira Pelu Woli Mike Adefisoye Lori Ogo Igbala Pelu Fowoshade Adefenwa

Woli Olorun Alaaye, Woli Mike Adefisoye Je Alejo Wa Lori Eto Ogo Igbala Titi Oni, Won Si Bawa Soro Lori Ominira Lowo Awon Ogun Orisirisi.

 

Oro Naa Kun Fun Imisi Olorun O Si Ni Iye Ninu Pelu, E Tele Wa Kalo