Skip to content

Oluko Ti O N Ba Awon Omo Jeleosinmi L’ajosepo

Oluko Kan N Ba Awon Omo Jeleosinmi Lajosepo

Oluko kan ni awon olopa ti gbe ni Ilu China ni ileewe alakobere kan. Loni ojo ru, awon olopa lo wa eni ti o gbe iroyin naa jade lati fi oro waa lenu wo.

Oluko ti a n soro re yii je obinrin, won si sowipe o n fi abere iranso gun awon omo ti ko ri orun sun gege bi Oniroyin ‘Xinhua’ se so.

Iroyin yii gba gbogbo aye kan lorii pe awon eniyan n fi Abere iranso gun awon omo ni ibi ti ko to sugbon awon eniyan miran so wipe Iro gbaa ni iroyin naa.

Oluko Mokanlelaadota Ni O Fidiremi Ninu Esi Idanwo Ti O Jade

Iroyin naa ko f’idi mule nitori wipe kosi ero CCTV nibe. Awon ibi ti Fidio CCTV ti jade; ki awon Olopa to debe ni won ti baaje nitori bi una se n lo ti o n bo.

Awon ti o n f’oro wanilenuwo so wipe Osise kan ninu yara ti won ti n so ile naa wipe ti Ero Monitor awon ba ti bere sii pariwo, Oun maa n fi ibe sile ni.

Awon olopa wipe ko si eri daju wipe won fi ipa ba enikeni lo po; won si ti iya ti o gbe iroyin naa jade lai ri eri-daju mole.

Awon Obi miran l’ose t’okoja sofun awon oniroyin wipe awon omode yii lo ogun oloro lojoojumo leyin ounje osan; won ni won sanwo fun awon lati le so iru oro beyen gegi bi ogbeni Xinhua se so.

Obi miran leyin ti awon dokita pe omo re fun ayewo to to jewo fun awon olopa wipe won sanwo fun oun naa lati jeri eke.

Leyin gbogbo atotonu wonyii, Ijoba dasi oro naa won si so wipe Iwadi Si N Lo Lori Oro Naa.