Oluko Mokanlelaadota Ni O Fidiremi Ninu Esi Idanwo Ti O Jade
Iroyin ti o tewa leti loni je ki a mo wipe awon oluko bii mokanlelaadota ni o fidiremi ninu idanwo ti a n pe ni Professional Qualifying Examination (PQE) ti awon egbe ti o n bojuto iforukosile awon oluko ni Nigeria; iyen Teachers Registration council (TRCN) ti ilu eko gbe kale.
Ogbeni Gbolahan Enilolobo, ti o je adari agba fun egbe iforuko sile naa sofun New Agency of Nigeria (NAN) ni ojo aje ni ilu eko wipe Mejilalenirinwo (412) iye oluko ni o joko fun idanwo naa eyi o je akoko re ni ilu Nigeria.
Ogbeni Enilolobo so wipe, fifidiremi awon oluko naa waye nitoripe awon oluko ayee’sin ko mo nipa ilo imo ero igbalode Computer. Beeni, pupo ninu won ko mo nipa ero igbalode rara; Idanwo naa si je eyi ti won fi ero igbalode computer se.
Idanwo naa waye nitori wipe awon Oluko ye ki won gba ase lowo egbe naa.
Gege bi Enilolobo ti so, awon Oluko ti o fidiremi naa yoo ni lati tun idanwo naa ko; ti won ba si tun fidiremi leemeta, awon yoo gba won danu.
Nnkan Meta Ti O Ye Ki A Fi Akiyesi Si Nibi Boolu Ti Nigeria Gba Pelu Argentina
“The failure of the teachers is due to their inability to use the computer; especially as it the first time they are using CBT for the examination.
“About three of the teachers exited without even completing the examination, indicating their being unfamiliar with the system at all.
“Those that failed will have to re-sit the examination.
“But if failure occurs consecutively for three times, it means automatic disqualification, and such teacher cannot be licensed,’’ gege bi nnkan ti o so.
O tesiwaju lati so wipe Ogbon (30) ninu awon Oluko naa ni o ti ni Iwe Eri giga iyen Masters ni o fidiremi ninu idanwo naa.
Ninu nnkan ti o so ni a ti gbo lede geesi wipe:
“The only PhD teacher also passed the examination.’
“Teachers should align themselves with computer so as to reduce the number of failures, and materials can be gotten from bookshops,” Enilolobo gba aeon oluko ni iyanju.