Skip to content

Olorun Yo Osere Adeniyi Johnson Ninu Ijamba Oko

Osere adeniyi Johnson wa laaye leyin ti oko re wa ninu ijamba oko ni ojo ayeye ominira Nigeria iyen independence day. Ninu fidio ti osere adeniyi Johnson gbe si ori ero abanidore, o so wipe;

E TUN LE KA: “Mi O Fe Oko Mercy Aigbe Ri O”-Bimbo Akinsanya Ki Gbe Sita

“How can a man come out of this alive? Well, i DID about 4hours ago… Don’t ask how, when and what happened… join me in thanking God!!! Mt redeemer liveth, Jesus is alive that’s why I’m sound OLUWA MODUPE!!!”

adeniyi-johnson-orisun adeniyi-johnson-orisun adeniyi-johnson-orisun