Skip to content

Ipe lati odo olorun ni atimole mi je”- Dammy Krane

Owo sokun olopa te Olorin Dammy Krane ti won ti mo le ni Miami ni 2nd of June fun jiji credit card ati identity fraud ni ilu Miami. Won fi esun mesan adigunjale kan ni  in Miami-Dade criminal court fun credit card forgery ati grand theft sugbon won ti gbe ejo na kuro ni court.

Krane ti so ni ori eroabanidore re snapchat wipe atimole oun je ipe lati odo olorun….dammy-krane-snapchat-orisun

 

dammy-krane-snapchat-orisun

Ni ojo Sunday, sept 10, 2017, dammy krane lo josin ni ile jiosin Cherubim & Seraphim Church of Houston ni Texas lati se idupe si olorun pelu iya re. Olorin Dammy Krane fi posts ibi ti oun ati iya re tin nkorin ni church si ero abanidore snapchat re….

dammy-krane-and-mother-orisun