Skip to content

Olorin Fuji Alao Malaika Ra Ile Nla Si Lekki

Ilumooka olorin fuji, Alhaji Sulaimon Alao Adekunle Malaika ti pari ile nla tuntun ti o n ko si Lekki Phase One, Lagos. Gegebi iroyin ti o n kan kakaakiri, Malaika n palemo lati se ayeye isile ni December odun yii.. Olorin Maolaika so eleyi di mimo ni ibi ayeye igbeyawo ti o ti lo korin; o so wipe;

‘It has happened. December has been fixed for my house warming ceremony. I will invite all my fans to be part of it’.

 

malaika-orisun