Skip to content

“Olori Wuraola Le Fe Okunrin Mi Bayi”- OOni Ife

Olori Wuraola ti da Owo Ori Iyawo Re pada. Ooni Ile ife ti kede pe yato si gbogbo nkan ti awn eeyan nso wipe okunrin ti o ba fe iyawo oun teleri ma se alaisi, Iyawo on le fe okunrin ti o ba wun nitoripe oun ti gba owo ori re pada lowo awon ebi re.

Hegebi Iroyin ti o te wa lowo lati owo The Boss Newspaper, won ti da Owo Ori Iyawo Teleri Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi pada fun oba, pe Olori Zaynab le fe enikeni ti o ba wun bayii. Iroyin tun so siwaju si wipe ooni o koko fe gba owo ori naa sugbon awon agbaagba ilu benin ni won tee ninu lati gbaa.

Igbeyawo aarin Ooni Ife ati Olori Zaynab (nee wuraola) fi ori sopon leyin ose Meji din L’ogun (18months) ti awon mejeeji n so wipe ko si nkan ti o jo be kii Olori Zaynab (nee wuraola) to kede oro naa lori ero abanidore Instagram re.