Skip to content

Ajo Olopa Ti Bere Itopinpin Lori Iku Ogbenii Ozubulu

Ajo Olopa Ti Bere Itopinpin Lori Iku Ogbenii Ozubulu

police-on-patrol-olopa-nigezie

Ni ojo kefa, osu kejo ti odun 2017, awon panipani kan wo inu ijo pelu ibon, won si pa awon omo-ijo. Nibe naa ni won si se awon miran lese.
Gege bi ohun ti a gbo, awon odaran naa wa lati ilu South Africa.
Awon Olopa gbo oro lenu awon won yii: President-General ti Agbegbe Ozubulu pelu Jovita Ofomota, Chairman ti Ebubechukwuzo Foundation titi Aloysius Ikegwuonu.
Iwadi je ki a mo wipe Ikegwuonu ni awon panipani yii to ipase re wa.
Aare ti Agbegbe Ozubulu development union (ODU), Dr Ernest Chukwuka be awon are ilu Nigeria wipe ki won ma se ro wipe ohun ti o fa ijamba naa ni eni ti won wa wa.
Gege bi Iwe Iroyin Vanguard se so, Chukwuka pe ipade awon asoju Ozubulu; won si so awon nnkan ti won maa se. “Laiparo, a si n daro, kayefi gidi si ni eyi je fun wa. O si ma gba wa ni asiko lati gbagbe oro yii, sugbon pelu atileyin Olorun ni egbe wa, A o bori isele
yii.
“One of the things we decided to do after our meeting, yesterday, is to visit the victims and give them some assistance.
“Lara ohun ti a gbimo lati se leyin ipade won lanaa, ni wipe ki a lo ki awon ebi ti oro yii se le si ati lati ran won lowo.

E TUN LE KA:  Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade
“Bi a se n se abewo si won ni ile iwosan ti a ti gbe n toju won, beeni a si gba oruko ati ilu ti won ti wa sile, ati wipe emi naa yoo lo se abewo si awon oloogbe ti o wa ni ile-igbokupamosi.
Gomina ipinle Anambra tele ri so wipe; Nnkan ti o sele yii je Ohun ajoji si awon Omo yibo, beeni awon eniyan pelu inuure si gbodo lodi si iwa naa.

E WO FIDIO MIRAN LOKE PATA-PATA