Olamide ti gbogbo aye n pe ni Baddo se gbe orin tuntun jade “WO” ti o si ti gba gbogbo ilu kan bayi, ti t’omode at’agbalagba si tin jo si lorisirisi. Igba ti orin Olamide yi jade, o se idije lori ero abanidore Instagram ti osi fun awon ti o gbe igba oreke ni 1million.
Laarin ose yi, Olamide pada si adugbo ti o ti se kekere ti o fi di ilu mooka Bariga lati lo ya fideo orin na pelu ajosepo oludari fideo Unlimited La…