Se Ese Ni Ki Obirin Bi Omo Koto Lo Si Ile Oko Emi?

  Se Ese Ni Ki Obirin Bi Omo Koto Lo Si Ile Oko Emi?

  Single Mother je nkan ti o je ajeji si asa ile yoruba. sugbon opo single mothers lo wa lawujo wa yala nipa iwakuwa tabi circumstances. Opo awon single mothers yi na ni won fe fe oko omiran sugbon ti won ma n ba ijakule pade. Ti okunrin ba ti e fi owo si opo igba ni awon obi won o ki n fi owo si.

  Ibeere wa lori eto ojuri yi ni wipe ” Se ese ni ki obirin bi omo ri, ki o si fe fe oko omiran ni ile yoruba?”

  E TUN LE KA: Kini ki n se: Iya Oko Mi O Je Kin Gbadun Tori Mo Ti Bimo Ri

  E bawa dasi….

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here