Olopa O Leto Lati Gba Owo Ki Won To Fi Eyan Sile

  Olopa O Leto Lati Gba Owo Ki Won To Fi Eyan Sile

  Police (Olopa) je ajo ti on gbe ofin ro ni ilu nigeria ti o sumo awon ara ilu. Opo igba si ni awon Olopa (police) ti ma n se bo se wu won. Awon ara ilu si ti pariwo si ijoba leti lori orisirisi asemase ti awon Olopa n se kakaakiri agbegbe wa. Lori eto Ojuri, atokun wa Ibrahim Ganiu gbe alejo won ti o je amofin (lawyer) wa sori eto lati yan nana gbogbo oun ti olopa leto ati se, ibi ti agbara won de ati eto ara ilu…

  E TUN LE KA>> Aare Mohammed Buhari Bere Ise Pada

  E wo Loke…

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here