#OJURI: Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju?

  #OJURI: Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju?

  Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju?

  Lori Eto Ojuri loni, Aralomo presenter bere lowo alejo re nipa awon nnkan ti awon omo le se lati fi ja fun eto won lati owo obi won.

  Bi awon omode se ni eto lati gba itoju gidi, aralomo bere nipa nnkan ti omo le se lehin ti ko ri itoju ti o peye lati owo awon obi re.

  E gbo nnkan ti alejo won so…..Nje eyin naa gba si nnkan ti won so yii??

  E Wo fidio naa Loke ⇑⇑

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here