LILO OMO NI ILOKULO (CHILD ABUSE): OJURI

  Ito suga
  Diabetes

  LILO OMO NI ILOKULO (CHILD ABUSE): OJURI

  ILOKULO OMO (CHILD ABUSE) KO DARA:

  Lori Eto Ojuri loni, eni-owo Adediwura Adeoye ati Wooli Adebayo Ayobami n soro lori eto omo’niyan [Human Rights]. Won jiroro bakanna lori ilokulo-omo-lona-aito ( Child Abuse ).

  Ninu oro Wooli Aybami, ilokulo omo je fif eto omo dun un tabi ki a ma lo omo ni ona to lodi si ofin. Won so siwaju pe opolopo ilokulo omo yi maa n bere lati inu ile.

  E TUN KA ELEYI NAA:  A MUST SEE FROM AYINKE AND BIMBO BADMUS (MILIKI EXPRESS)

  Eni-owo Adeoye so wipe gbogbo obi gbodo mo wipe omo ni eto si ounje, eko, agbegbe, ati aso ti o dara.

  **Fun ekunrere, e wo fonran ti o wa nisale yi:

   

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here