E Gbami: Oko Mi Ma N Na Mi To Ba Fe Bami Lajosepo

  orisun-ojuri-crying woman-orisuntv

  E Gbami: Oko Mi Ma N Na Mi To Ba Fe Bami Lajosepo

  Sex and Relationship:

  Arabirin kan lo fi atejise yi ranse si atokun wa lori eto Ojuri, O so wipe gbogbo igba ti oko ohun ba fe ba ohun ni ajosepo ni o ma n na ohun. Looto, oko daadaa ni, o si ma n toju ohun, sugbon kini kekere yi ni kan lo baaje….. Kini ki ohun se?

  E TUN LE WO: #Isembaye: Eegun Ile Ati Idi Ti A Fi N Bo Eegun

  E wo ni bi yi>>>>

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here