Skip to content

#OjumoIRE: AWỌN NNKAN TI O YẸ KI ỌMỌ ṢE FUN AWỌN OBI (Gẹgẹ BI Ojuṣe)

#OjumoIRE: AWỌN NNKAN TI O YẸ KI ỌMỌ ṢE FUN AWỌN OBI (Gẹgẹ BI Ojuṣe)

Gbogbo wa ti a ni obi, Yala awọn ni wọn bi wa ni tabi awọn ni wọn tọ wa dagba, Obi ni obi n jẹ. Awọn miran ni iya ti awọn miran si ni baba. Ni’bomiran, awọn kan ko ni iya bẹẹni wọn ko ni baba. Pataki ọrọ wa loni ni awọn nnkan ti o yẹ awọn obi wa gẹgẹ bi ọmọ.

Lori Eto Ojumọ ire ti ọsẹ yii, Ọwọ adura pẹlu alejo re ti o jẹ oludari agba fun Ijọ Hasbunallahu sọrọ nipa nnkan ti o yẹ ki ọmọ ṣe fun obi.

Lara awọn nnkan ti wọn sọ ni ITỌJU ati awọn ohun miran ti o le mu inu awọn obi wa dun.

Ẹ wo fidio yii fun ẹkọ kan ati omiran lori akori ọrọ naa.