Skip to content

Ojowu Ọkunrin Kan Sa Ololufẹ Iyawo Rẹ Atijọ Pa

Ọkunrin Kan ni ọwọ awọn ọlọpa mu in Ilu benue Wipe Opa Ololufẹ Iyawo rẹ Igbakan ri.

Ọkunrin naa ti orukọ rẹ njẹ Abunde Guje ni Ọwọ Awọn Ọlọpa Tẹ Ni agbọ wipe o fi agidi wọ ile Iyawo rẹ atijọ O si da Acid si ni ara, lẹyin naa ni o fi Ake Sa Pa.

Iyawo rẹ atijọ eyi ti o bi ọmọ meta fun ni O fi Ẹjo Sun ni agọ Ọlọpa, O si wipe Niise ni oun ati Ololufẹ Oun Titun wa ni ile, Ni Abunde ati Awọn kan Wọle Wọn si ṣa Ololufe oun titun Pa.

Tags: