Skip to content

Ohun Ibaje Ti N Sele Ni Mosalasi Shekau

Ohun Ibaje Ti N Sele Ni Mosalasi ; Abubakar Shekau ni oso eyi

Ogbeni Abubakar Shekau ti gbogbo eniyan mo si asoju ati oga awon iko Boko Haram tu ti fi fidio titun sita ni ojo aje January 16 2017.
SHEKAU
Ninu fidio ti fi sita, ni o ti soro nipa adoloro ti won ju si ile-iwe giga Maiduguri ni Ipinle Borno (Uni.Maiduguri) ni aro kutukutu ojo aje ati idi ti won fi ju.
Ninu oro re, o so wipe awon momo ju si ibe ni nitori ohun idoti ati opolopo ibaje ti n sele ni inu mosolasi ti ile iwe na ti ko si ye ko ribe nitori pe o ye ko je ile adura ki egbin kankan ma si se sele ni inu re.

“Ado oloro ti o dun laaro eni, (Ojo Aje) awon omo mi ni mo ran ki won se. E ma se ma puo tabi pidan fun awon eniyan pe ile Olorun ni Mosalasi na nitori opolopo ohun idoti ni e n danwo ninu re ti ko si to rara”, Shekau wi.

“A ko ni ija pelu awon omo Nigeria, a ko si binu siwon nitori won ko se iku pa nikeni niigbo Sambisa. A wa n gba ladura pe a o ni yi pada nitori Korani ni ouko wa ati pe ohun ti o ko wa ni awa n se”.

Siwaju si Shekau so pe “IFIRANSE FUN BUHARI NI!…. SE IWO LAGBARA TO OLORUN NI”?

buhari

“Emi Shekau ni mo n soro, mo wa laye mo wa alaafia ati ara pipe. Ko si ohun ti awa so pe ama se ti a o ni se. Koda ki Oba Farao jewo ese re ki o si toro idariji, awa ko ni jewo, a o si ni toro idaraji !

Awon apaniyan meji ni o lo ju ado oloro na si ile iwe giga Maiduguri ( UNIMAID). Ado oloro kini dun ni mosalasi na ti owa ni inu il- iwe na ti won si so ikeji si enu one kaarun (Gate 5) ti ile-iwe na

Awon eniyan ookan-le-logun, ni won se agbako, awon meta-din logun wa ni ile iwosan, ti awon meerin eyi ti oluko agba kan (professor) wa larin won si fi iku se ifa je.