Ogorin Milionu Eniyan Ni Nigeria Ni Ko Gbadun Ina Manamana Daada
Eniyan bi Iye Ogorin Milionu ni orile Ede Nigeria ni won so wipe ko gbadun ina ijoba ti o ye.
Gegebi Atejade Banki Agbaye, Ilu kereje bii 8,000 ni orile ede yii ni ina ko de odo won.
Agbenuso fun Banki Agbaye, Ogbeni Mac Cosgrove-Davies, so eyi nibi ayeye “Fourth Mini Grid Action Learning Event: titled, ‘Up scaling Mini Grids for Low-Cost and Timely Access to Electricity’ ni ilu abuja lojo isegun t’o koja.
Cosgrove-Davies so wipe mefa ninu mewa eniyan ni gbogbo agbaye ti awon kojo ni o n gbe ni ilu Africa lai gbadun Ina Ijoba. o wipe, Ijoba apapo ti bere fun iranlowo Banki agbaye fun awon ise kookan ti yoo de ibi Ina manna-manna.
Agbenuso Banki Agbaye naa wipe,
“We know what is at stake: globally, more than one billion people still lack access to electricity; Sub Saharan Africa is home to about 600 million of these.“In Nigeria, 80 million people are without access, and millions more suffer from poor service. Rural Electrification Agency expects mini grids to fill a substantial portion of that gap covering up to 8000 villages nationwide.“This is not a job for any one of us alone. The government of Nigeria is pushing hard toward universal electrification.”
O tesiwaju,
“The Nigerian government has asked the World Bank’s support for a National Electrification Project that focuses on off-grid opportunities including mini grids and the World Bank is delighted to respond to this request.“We know that our development partners – many in this room – are also standing shoulder-to-shoulder with government on this effort.“For the World Bank’s part, the National Electrification Project fits well into a broader energy portfolio in Nigeria which aims to holistically support sector development. Together with all of you, we are seeking to help our Nigerian colleagues make the most of international expertise and experience as it fits the Nigerian setting.”
Cosgrove-Davies be awon agbaagba lowe lati dasi toloun bi agbara won ba ti mo fun ilosiwaju ise nla naa.