Oge Sise: Itoju Awon Oun Ti A N Lo Si Ara Wa
Atokun wa, Torera ni eto Eji Owuro se alayi lori itoju awon oun ti a n lo si ara wa. Leyin itoju ara wa nipa wiwe dede ati awon oun miran, a si le ni awon arun die die nitori eyi ni a se nilo lati toju awon oun ti a fi toju ara wa.
Ewo fanran yii fun ekunrere:
