Skip to content

Ogbeni Reno Omokri So Wipe Iro Ni Tinubu N Pa Nipa Pe BUHARI Ti Mu Ileri Re Se

Ogbeni Reno Omokri So Wipe Iro Ni Tinubu N Pa Nipa Pe BUHARI Ti Mu Ileri Re Se

Ni Ana ode oni, Oludari-agba fun egbe APC; iyen Ogbeni Bola Tinubu jade lati so wipe ise takun-takun ni Buhari ti gbe kale lati igba ti o ti bere ise. O wipe lododo, Buhari ti mu awon ileri re se; beeni o si ye ki a dibo fun-un ni odun 2019.

Sugbon o yanilenu wipe, ogbeni Reno Omokri da lohun wipe Iro palaba ni o n pa wipe oun ko ri ise kan pato ti Buhari ti gbe Ile-aye se lati igba ti o ti gori oye; gbogbo nnkan ti o ti se ileri wipe oun yoo se ni ko fowo ba.

Ogbeni Reno tesiwaju wipe: awon nnkan bii iye owo Naira kan si Dollar ti Buhari pinnu lati gbe wa sile, beeni awon ise ti o so wipe oun yoo gbe kale fun awon odo kaakakiri orile ede Nigeria ati beebee lo.

E wo oro ti o so ni pato ni ede geesi:

 

reno-omokri-orisun-buhari reno-omokri-orisun-buhari