“Odunlade Adekola ko ni baba omo mi, ibasepo Oga si omo ise lo wa ni aarin wa”… Eyi ni oro ti osere bukola adeeyo fi ranse si gbogbo eniyan ti o n gbe iroyin pe odunlade ni baba omo ti o se bi nibi ose die seyin… O so eleyi di mimo ninu atejise ti o fi ranse si ori ero abanidore re nigba ti iroyin na ti kan kakaakiri….
Nkan ti o so re>>>