Skip to content

E Gbagbe Pe Odun Ti De, Kosowo Ni Apo IJOBA O – LAI MOHAMMED

E Gbagbe Pe Odun Ti De, Kosowo Ni Apo IJOBA O – LAI MOHAMMED

Minisita fun iroyin ati Asa ni Ile wa, Ogbeni Lai Mohammed ti pariwo sita wipe Ijoba apapo ko ni owo ti o to lati fi se awon nnkan miran fun Odun 2017

Ni Ojo aje ni minisita naa so wipe awon yoo ma duro lati le pe odi fun eto isuna fun odun 2018 niwaju awon Ile igbimo asofin.

Lai Mohammed so ni ede geesi wipe:

it is not that government is deliberately withholding releases to fund the 2017 budget or starving us. It is because we do not have enough money to do that.

“When budgets are made, they are made based on certain assumptions and if you are not able to get enough to meet your assumptions, there will be poor release.

“At least, there is an improvement in different sectors like the Nigeria Customs Service, while the price of crude oil is getting better. There is also more peace in the Niger Delta. So we can produce more.”

Oro ti o jade leni Lai Mohammed yii gege bi nnkan ti a wadi lodi si oro enu minisita fun owo ati kiko oro jo fun Nigeria, Iya afin Kemi Adeosun ti o so fun awon onisowo ti ilu faranse (French) ni ojo Aje December 11 2017 wipe Iye owo ti o to N1.2 Trillion wa nle fun awon Ile Ise Iranse (ministries), awon Ijoba elekanka Departments and Agencies (MDAs). O wipe owo naa wa fun awon nnkan ti won ko sinu bojeeti odun 2017.

Minisita naa so wipe Ijoba fi iye owo N450 billionu naira fun awon ise olowo nla ti iye owo N750 Billion ti o jasi N1.2 Trillion yoo wa fun igbedide orile ede yii.