
Oludije Fun Aarẹ Orilẹ Ede Naijiria Ni Abẹ Asia Allied Congress Party of Nigeria (ACPN) ati Minisita fun Ẹko Tẹlẹri; Arabirin Oby Ezekwesili ti jawo Ninu Idije Sipo Naa.
Ẹ Wo Nnkan Ti Awọn ẸṢỌ Ẹnu Ọna House Of Assembly Ati Oṣiṣẹ Ibẹ Ṣe Si Ile Naa
Oby Sọwipe; Igbesẹ yi yio jeki oun le fi ọgbọn kun ọgbọn pẹlu oludije miran lati parapo fun Ijọba Tiwantiwa Ni Ẹyi ti o yatọ si Ijọba All Progressive Party (APC) ati Peoples Democratic Party (PDP)
Buhari Sowipe O Soro Fun Ohun Lati Padanu Ibo Odun Yi
Ọrọ yii ni o di mimọ lori ero twitter re ni aarọ ọjọbọ.