Skip to content

Obasanjo Tabi Baba’sale Kan Ko Ran Mi Ni Idije Fun Ipo Aare Odun 2019 – LAMIDO

Ki awon eniyan ma ri Alhaji Sule Lamido gege bi eni ti won n ti tabi eni ti o ni atileyin Baba’sale kan, O pariwo sita wipe ko si ajosepo kankan laari oun ati Obasanjo lori igba ibo ti oun gbe fun ipo Aare orile ede yii ni odun 2019.

Lamido so oro yii ni igba ti o n ba awa oniroyin soro ni ipinle Plateau ni ojoru. Gege bi a ti rii gbo, ki won to se ipade gbogboogbo ni October, o lo si ipinle naa lati lo bebe fun ibo.

Gege bi o ti so ni ede geesi:

“I have no political godfather; the presidency is for matured minds and I am one.

“I hear people say Obasanjo is the one sponsoring my presidential ambition. That is not true.

lamido-sule-obasanjo-buhari-2019-pdp

“I was in PDP before Obasanjo became president, but I respect him as my leader and elder statesman. I also respect every aspirant contesting on the PDP platform.”

He said that his goal was to salvage Nigeria from poverty, underdevelopment and economic stagnation, adding that he was not desperate for the party’s ticket.

“I am not desperate for the ticket. The Presidency is not just about me because all the aspirants in our party are working for a common goal.

“If I am not made candidate of our great party, I will support whoever emerges as our flag bearer,” ko je bi o ti wi.

Lamido so wipe oun n bo pelu opin si gbogbo wahala ti awon oloko n dojuko pelu awon fulani ti o n paniyan kiri ni orile ede Nigeria ti won ba dibo yan oun ni odun 2019.

Ki o to di asiko naa, Oloye Damishi Sango so wipe ibo-aarin egbe ti ko ni madaru tabi ireje kankan ni yoo waye laarin egbe PDP ni odun yii.

lamido-sule-obasanjo-buhari-2019-pdp-Sule-Lamido-in-police-net