Obaeze se ileri lati yo Adeboye nipo olootu agba RCCG.
O sese ko je wipe, ofin ti o je ki Olusoagutan Enoch Adejare Adeboye fi ise sile gegebi asoju agba ati alamojuto Redeemed Christain Church Of God(RCCG) je atowoda eniyan kan.
Jim Obaeze ti o je akowe agba fun eto isoro ni owo ti Nigeria (FRC) nigbakanri lo fi idi ofin yen mule, o de ti seileri lati yo Adeboye kuru nipo
Ogbeni Segun Adegbiji ti o je agbenuso fun RCCG lo fi eyi se mimo ni ojo kejila osu January ninu ipade ijo na pelu awon oniroyin ni Ipago Redemption Mowe, ni Ipinle Ogun.
Siwaaju si, Ogbeni Adegbiji so wipe Obaeze ti fi igba kan ri je Olusoaguntan ni RCCG ti o de fi ise sile fun idi ti o ye ohun nikan. O wipe Obaeze je oluko ni “School of Disciples” sugbon o fi ise sile lai se wipe enikeni le tabi da duro. o de bere si ni josin ni RCCG province 11 to wa ni Acme lagbegbe Ogba ni ilu Eko.
“Ko fi igba kankan si ija laarin Obaeze ati ijo Olorun sugbon mo gbo wipe o se ileri lati yo Adeboye kuru”.
Adeboye ti o ti je asoju ati almojuto RCCG fun igba to le ni ogun odun, fa elomiran sile bi asoju Nigeria lai pe yi nitori ofin ti ijoba fi sile pe awon alamojuto agbari ti ko pa owo si apo ijoba bi ile-ijosin, mosalasi ati bebelo ko gbodo lo ju ogun odun lo.
Ofin yi ti mu ki Adeboye yan Joshua Obayemi keke asoju lehin re.
Lotito ijoba apapo ti da ofin na pada sugbon Adegbiyi fihan pe Adeboye ko ni gbada si ise gege bi asoju RCCG Nigeria nitori pe ti a ba mo Adeboye dada a ma mo wipe ko le gbe iru igbese beyan lai gba ase lowo Olorun ati lai fi to awon oga agba ijo leti. O so wipe ipinnu yi ko fi ibi kankan da Adeboye duro gege bi alomoojuto gbogbo RCCG lapapo.
Gege bi se mo, RCCG je ijo ti o n gboro ti o si ti wan ni orile-ede igba-din-meji ti o si je gbogbo orile-ede ni ni o ni alamojuto tiwon. “Nitori na, ko si ohun to buru ti orile-ede Nigeria ti ori ijo wa na ba ni alamojuto tie nipa be ko si idi kankan lati da ipinnu na pada”
Amo sa, ipinnu yi ko fi ibi kankan di olootu agba Adeboye lowo nitori ohun ni gbogbo awon alamojuto RCCG ni orile-ede to ku n jabo fun.
Obayemi je igbekeji ni eto isuwo ati omo egbe igbimo alakoso ni RCCG ki o to po si ipo alamojuto RCCG gbogbo Nigera.