Skip to content

O Damiloju Wipe Eyin Omo Nigeria Yoo Dibo Funmi Leekansii – BUHARI

O Damiloju Wipe Eyin Omo Nigeria Yoo Dibo Funmi Leekansii – BUHARI

Muhammadu Buhari ti fi idaniloju re han wipe awon omo Nigeria yoo dibo yan oun leekan si ni Odun 2019. Pelu Idaniloju ni Are se so eyi nibi abewo re si ilu Kano ni ojo kefa osu yii (December 2017).

E TUN LE KA: Idi Ti ATIKU Fi Pada Si Egbe Oselu PDP

Nibi abewo olojo meji naa, Buhari yoju si Muhammadu Sanusi III ti o je Emir Ilu kano; awon ero si jade lati wa gbaa pelu atileyin awon loruko-loruko ile naa. O wipe, “Eyi ni o funmi ni Idaniloju wipe oun yoo wole saa ikeji ni Odun 2019.

Ni Ede geesi, o wipe:

“I am overwhelmed by the sea of people I see, and by what I see today, if elections are contested I will no doubt win it,” he said.