Skip to content

Nkan Ti Mercy Aigbe Ati Omo Re Michelle Fi Jo Ara Won

Nkan ti Mercy Aigbe ati omo re Michelle fi jo ara won

Olorun fi arewa odo’mobinrin omo odun merin din logun Michelle Gentry ta Mercy Aigbe lo re. Arewa odo’mobinrin alawo dudu naa fi ewa re han o si tun feran lati maa se bii ibeji iya re ni gbogbo igba.

Ibasepo iya ati omo ti o wa laarin Mercy Aigbe ati omo re l’agbara gan, awon eyan le jeri si nitori won jo maa n wo aso kan naa lo si ibi ayeye.

E tun le ka: Yomi Fash-Lanso se alaye nkan ti baba je

Bi o tun se so:
I am Super Super proud of you Michelle @michelleio__ , she took my brain

Aworan naa re:

Nkan ti Mercy Aigbe ati omo re fi jo ara won