Skip to content

NKAN TI AWON EEYAN NSO NIPA ORO TI TIWA SAVAGE SO

ILUMOOKA TIWA SAVAGE TI SO ORO NIPA NKAN TI O RO LORI GENDER DISCRIMINATION. O SO ELEYI NI IBI IFOROWANILENUWO PELU ASORO LORI ERO RADIO BEATFM Toolz oniru lori eto re The Midday Show nigba ti won bi leere nipa oro naa.

Tiwa savage so wipe obirin ni gbogbo ibi ma n tiraka ju awon okunrin lo ninu gbogbo nkan ti won ba n se ki won to se aseyori ti ko de ri be fun awon okunrin. “It’s real. I’m not going to say I’m completely comfortable with it but it is what it is. You have to deal with it. If it means you have to work 10 times harder than your male counterparts, don’t complain about it, do what you have to do. We all celebrate people like Oprah and Mo Abudu and we don’t actually realize what they have to do to get to that point. They probably had to do 20 times than their male counterparts. Once you get there, you don’t complain about how you get there. So, whatever it is you have to do as a female, you just have to get it done,”
Tiwa Savage tun so siwaju si ninu oro re wipe okunrin ati obirin o kin n se ikanna, o so wipe obirin gbodo mo wipe ko si bi won ba se le so orire to, okunrin sin i olori won; “I know I’ll ruffle a few feathers but I also don’t think men and women are equal, I don’t think that’s how God created us that way… especially in the household anyway. So I think as females when we realize that yeah we can be strong in our career, but when we are home we have to realize that the man is the head of the house,”

Opo eeyan ni ko fi owo si nkan ti Tiwa Savage so, ti won sit i bo si ita ni opo lopo lati fi ehanu won han…. Awokan se n ki Tiwa leyin fun oro to so, ti won gbe oriyin fun pe o gba awon okunrin ni oga… e wo won:

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun

 

 

Bee nan i awon kan wa, ti won so wipe inu awon o dun pe tiwa savage le je okan lara awon ti o n fa obirin seyin; e wo won:

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun

tiwa-savage-orisun