Skip to content

Nkan ti Wizkid ni lati so nipa ibi-ise ati eku Aare Buhari

Wizkid ati okan ninu awon ololufe jo so oro kan, leyin ti o n pete-pero lati gbe orin kan kale ni aago kan osan sugbon  o ji ni aago meji koja iseju marun le ogun osan.Oga ile-ise starboy naa so oro kan si Aare Buhari nigbati o n ba okan ninu awon ololufe orin re soro lori twita.Aare wa sese si ilu Nigeria ni ojo Kankandinlogun osu kejo, ojo satide, leyin tio lo ojo meta le ni ogorun ni ilu oyinbo fun itoju lori aisan ti akomo.

E TUN LE KA: Davido Lo Pe Mi Lati Ko Remix Living Things-9ice

Oludamoran agba si Aare Buhari Shehu Garba so lori iroyin ati ikede wipe ibi-ise Aare naa n fe atunse nitori irewesi nipase awon eku nigbati Aare ko si ni ile.