Skip to content

Ti Won Ko Ba Dibo Fun Mi Laarin Egbe PDP, Mi O Ni Fi PDP Sile – SULE LAMIDO

Ti Won Ko Ba Dibo Fun Mi Laarin Egbe PDP, Mi O Ni Fi PDP Sile – SULE LAMIDO

Gomina ipinle Jigawa teleri ti o kede ijade re lati dije ni odun 2019 fun ipo Aare orile ede Nigeria labe asia egbe PDP (Peoples Democratic Party) so wipe oun ko ni fi egbe naa sile fun idi kankan koda ki oun fi’di remi nibi idije odun 2019 naa.

Lamido so ninu iforowanilenuwo ti a se fun-un ni ile Gen. Jeremiah Useni nibi ti o ti lo se abewo si ilu JOS ni ojoru ti o koja.

A gbo wipe Ogbeni Lamidoo ti o gbera lati lo si ofiisi awon egbe PDP ni ipinle Plateau pelu okan lati so wipe oun n lo fun ipo Aare orile ede Nigeria ni odun 2019.

Ni ede geesi o wipe:

lamido-sule-obasanjo-buhari-2019-pdp

 

“All of us vying for Presidency in PDP are equal and are capable of ruling Nigeria as President.

“2019 Presidency is not just about me, we are all working for a just and a common goal to salvage the country. So if I’m not made candidate of our great party, I will support whoever emerges as flag bearer for PDP.”

O wipe oro awon egbe naa yoo pada wa si imuse sugbon ki gbogbo eniyan lo mo wipe kiise Olusegun Obasanjo ni o fun owo lati dije fun ipo aare, beeni ko gba oun ni amoran kankan lori igbese naa ti oun gbe. O tesiwaju lati so wipe ko si baba’sale kan fun oun ninu iselu orile ede Nigeria.

Ni ede geesi o wipe:

“I was in PDP before former President Olusegun Obasanjo became president, I do not have a godfather, but I respect everyone in our party; we have the same aspiration as PDP members,” he said.

The presidential aspirant said if voted into power, his administration would tackle security issues head on and try to find a lasting solution to the herders/farmers clashes being experienced in some parts of the country.

Earlier, the party’s state Chairman, Mr  Damishi Sango, promised the aspirant of the state party’s support while urging him to strive towards making a difference if he emerged as the party’s candidate.

lamido-sule-obasanjo-buhari-2019-pdp