Skip to content

E Ye Maa Gbe Ofofo Oro Ti Ko Sele Mo – Ajo NAN Lo So Fun Awon Akeko Bee

Egbe awon akeko ni orile Ede Nigeria ni ojobo ti o je ojo kejo osu Erele inu odun yii ti fi ibawi lele lori bi awon akeko se n lo ero alatagba social media; ti won se n fi tan iroyin ti ko je ooto kale kaakakiri orile ede Nigeria; awon iroyin ti o le fa ainife ni gbogbo ibi.

Agbenuso fun egbe NANS, ogbeni Bestman Okereafor so ninu atejade ti won fi jise siwa ni ilu Enugu wupe ki awon omo-ileewe ati akeko labe botiwukori ma se gbe iroyin sita ti ko ba si eri ododo ninu re nitori wipe o le fa idiwo fun alaafia ti o ti n gbile ni Orile ede yii nipa Eto Eko.

Gege bi o ti wi ni Ede Geesi:

“The attention of the apex students’ governing body under the auspices of NANS has been drawn to a purported voice note and old pictures of an attack that happened in Ogun in circulation. “It should be noted that the Nigeria Police Force, Ogun State Command, under the watch of Commissioner of Police, Mr Ahmed Iliyasu, remains pro-active and second to none in the country. “People, especially students spreading false rumours about the security status of the state should desist from such act.

“Gov. Ibikunle Amosun has over the years made security a priority in the government’s agenda, which indeed has fetched him several awards and laurels,’’ he said. The NANS spokesman said that the association had confidence on the Ogun State Police Command. “So, the purported voice note and pictures about herdsmen attack along the Lagos/Ibadan Expressway, currently in circulation is not true and totally false and should be disregarded by the public. “Furthermore, students should endeavour not to be used as political instruments by some desperate dare devil politicians,’’ he said.

NANS-protest-akeko

 

Tags: