OFIN TI YOO MU IDAGBASOKE WA SI ILU EKO

idagbasoke

Awon egbe ile igbimo asofin ti so wipe awon ko ni duro lati mu idagbasoke ba ilu eko. HON. Fafunmi Dayo joko ti awon ara ilu, won si fi okan won bale pe Idagbasoke yoo de ba Ilu eko. Awon fijilante ati awon olopa naa soro lori bi ilu eko se maa lo siwaju.

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here