Alhaja Otibiya Pe Awon Eniyan Ki Won Ran Awon Odo Lowo

Otibiya

Alhaja Otibiya Pe Awon Eniyan Ki Won Ran Awon Odo Lowo

Alhaja Azeezat Lawal pe si awon ti ori se igi ola si ni awujo lati ma ran awon odo ti o ni ebun lowo fun idagba soke ebun won.

Oro yi ni Alhaja Azeezat  so ni ibi ayajo Otibiya ti won se ni ojo kejidiniogun osun kejila odun yii. (18/12/2016) ninu gbongan LTV. Ayajo otibiya o hun ni won gbe kale fun awon odo ti o lebun orin pataki julo orin Islam, ti won o si ri eni gbawon jade.

E wo fanran yi fun ekunrere iroyin

 

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here