#OrinTitun: Harrysong – Journey (Irin Ajo)

Ọga kpata kpata Alterplate Records Harrysong Ti A Mọ si Ọgbẹni Songs Ni O ṣẹ gbe Orin tuntun kan jade eyi ti o pe ni Journey, Ti o tumo si Irin Ajo ni Ede Yooba.

Ẹ gbo Orin Tun tun Na Ki E Je ki a mọ bi ẹ ti fẹran rẹ too

Ẹ Danlodu Rẹ Nibi

2 COMMENTS

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here