Skip to content

Are Muhammadu Buhari Lo Pade Awon Omo Ti Won Tu Sile

Are Muhammadu Buhari ti ran awon igbimo minisita losi Dapchi ni ipinle Yobe lati lo fi oju ba ipadabo awon omo akeeko-binrin ti awon iko Boko Haram ji gbe ni osu kan sehin.
Egbe Iko Boko Haram tu awon omo yi sile ni aro ojo Isejun, 21st March 2018 ni igba ti iroyin kan wa pe won wa omo lo ba awon ebi won ninu oko.
Awon Minisita ti Are Buhari ran lo sibe ni Minisita fun Iroyin, Lai Mohammed, Minisita fun Oke Jina, Abdulrahman Dambazau ati Minisita fun Oke Okun, Khadija Ibrahim.

Nibayi, Ijoba Apapo ti fi di mule pe Okanlelogorun (101) ninu awon omo akeeko ti woni won ti tusile ninu awon adofa (110).