Gernot Rohr ti fidaju pe agbaboolu super eagles victor moses ati john mikel obi ma pada lati gba boolu koju cameroon. Nigeria ma koju cameroon ni uyo ni ojo Jimoh Friday, September 1 ti won yoo si gba ese keji ni yaounde ni ojo aje Monday, September 4 fun 2018 FIFA World Cup qualifiers.
Siwaju idije yi, Moses ati Mikel Obi ti won o ti gba boolu fun super eagles lati November 2016 ma wa layika lati gba boolu gege bi adari iko super eagles Rohr se so… “We have recovered some injured players – Mikel Obi is coming back, we missed him so much in the last game. We have also Victor Moses and (Leon) Balogun, both are also coming back from injuries, we missed all of them,”
E TUN LE KA: Super Eagles Fi di Remi Ni CHAN Qualifier
Ewe Gernot Rohr, kominu si aisinle goalkeeper Carl Ikeme ti o n gba itoju fun aisan acute leukaemia….“Unfortunately we don’t have our goalkeeper Carl Ikeme, who is sick, but we will do it for him, we want to win for him and to bring him with us to Russia”.
Moses ati Mikel Obi pa ere boolu abanidore laarin super eagles pelu senegal ni March. awon mejeji naa o si n le fun idije abanidore pelu corsica ati togo pelu 2019 Africa Cup of Nations (AFCON) pelu South Africa ni June.