Skip to content

Mo Ti Gba Olopa Meta Lati So Ile Mi-Bobrisky

Arakunrin ti o feran lati maa mura bi obirin, Bobrisky ti bo si ori ero abanidore instgram page re lati dan enu nipa igba aiye nla ti o n gbe. Arakunrin oun ti yoo ero agbaorosile (comments) kuro lori ero abanidore instagram re,

o ko wipe;  “Am not their mate Bobrisky is classy, and intelligent . Am on top of my game no time for shit. I have three securities two police men guarding my house . I don’t make friends cos I don’t need them.”

 

E TUN LE KA: “Asiri Ti O Wa Leyin Ori Mi To Pa”- Papa Ajasco

Oruko abiso Bobrisky ni Okuneye Idris Olarenwaju ti won bi ni Odun 1992, O pari ile iwe secondary re ni King’s College ni ilu eko, ti o si pari eko re si University of lagos (UNILAG)