Skip to content

Mo Ma Mu Buhari Larada Ti O Ba Wa Si Odo Mi- Satguru Maharaj Ji

Oludasile One Love Fam, Satguru Maharaj Ji ti so wipe oun le mu aare orileede nigeria mohammed buhari lara da ti o ba wasi ile ijosin oun fun adura. Satguru Maharaj so eleyi nibi ti o ti n ba awon oniroyin soro ni Nigerian Union of Journalist, NUJ, Secretariat in Alausa, Ikeja, Lagos state.

E TUN LE KA: Awon Aanfani Keke Marwa Yato Si Moto Tabi Okada

“I do not believe in sickness. The President of Nigeria is great and he should remain so. And that is why if he comes to me for healing, I will heal him. I have done it for several public officeholders. I remember that I treated Ibrahim Badamosi Babangida, IBB, when he was afflicted by an ailment in his leg. I cured him. But he later denied me. That was why the ailment returned” 

Satguru Maharaji kun adele aare Yemi Osibanjo leyin fun gbogbo ise takun takun ti o n se ni orileede nigeria ni aisinle aare Buhari. Satguru Maharaji so siwaju wipe aare Buhari ma padawa si lile lati dekun gbogbo oro ti o n lo kakaakiri orileede nigeria