Skip to content

“Miliki” Ma N Pa Ironu RE… Nje E Gba?

Miliki tabi Faaji ko iha orisirisi si gbo eniyan. Bi awon kan se ri Miliki si mimu oti pelu ore awon kan ri gege bi gbigbo orin asiko, elo miran si ri bi Ijo ati didaraya.

Eyikeyi ti o ba je, AYINKE KUJORE ati BUSOLA FUNKY ELLE yannana itumo Miliki lori eto won Miliki express asi tun jade sita lati mo ohun ti won ro pe anfaani miliki je…..

 

E TUN LE WO:Bi A Se Le Je Igbadun Opin Ose Lai Fi Pa Ojo Ise Lara

 

E wo ni bi yii>>>>