Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni

Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni

Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni

Yetunde ObaNla pelu LARA OLUBO joko lori eto toni lati so isipaya ti o faa ti awon se yipada lati inu esin Musulumi si ti Kiriyo gege bi baba Yetunde Obanla se maa n pee.

Omo Alhaji bi awon miran ti maa n pe je Olokiki akorin ti awon eniyan maa n pe ni OYI BIRI ti o jeyo lati ibi ti o ti korin “O Yi BiriBiri Kan Mi O” ni odun ti o koja seyin.

Mrs Obanla je eni ti o wa lati idile elesin Islam ti aye n pe ni Musulumi. A bii sinu idile Alhaji ati Alhaja Fatai Obadairo. Ni Odun 1999 ni o si dara po mo esin kristieni ni odun naa labe Dr. Dr Ebenezer Obey Evangelistic ministry.

Nnkan Meta Ti O Ye Ki A Fi Akiyesi Si Nibi Boolu Ti Nigeria Gba Pelu Argentina

E wo fidio ti o wa loke yii ki e le mo bi o ti yipada si esin onigbagbo.

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here