Orin Ni Mo N Ko Kin To Ya Mo Ise Theatre- OYITA

Orin Ni Mo N Ko Kin To Ya Mo Ise Theatre- OYITA

Oyita gegebi awon ololufe re se mo si je osere ere agbelewo ti o se fowo ro seyin ti o si ti wa ni idi ise yi fun igba die. won ni anfani lati wa si ori eto wa Miliki Express pelu ayinke ati bimbo won si bawa so oro lopo lopo. Won soro nipa bi awon se di eni ti n se ere agbelewo ati nipa orisirisi ti n sele lori set ti won ba n se ere agbelewo…

 

E TUN LE KA: Ko Si Eni To Ni Iru Awo Orin Mi Ni Nigeria- KOFFI

 

E TUN LE WO:

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here