Ipa Ti Osere Obirin N Ko Ninu Ere Lo N Fa Iwokuwo Won- Olajuwon Adewunmi

Ipa Ti Osere Obirin N Ko Ninu Ere Lo N Fa Iwokuwo Won- Olajuwon Adewunmi

Ni enu ojo meta yii, opo eniyan lo n soro nipa iwokuwo awon osere obirin wa ninu awon sinima agbelewo wa, ti awon osere gan ni oro kan tabi meji so lori oro naa. Osere Olajuwon Adewunmi ti o ti se opo ere agbelewo je alejo lori miliki express pelu bimbo ati ayinke won si so oro lori akori yi… Arabirin Juwon so wipe awon ipa ti won ma n ko ni o ma n fa iwokuwo… e gbo si wa ju si ninu fidio yii…

E TUN LE KA: Didekun Iwokuwo Awon Osere, Ise NFVCB Ni -Femi Adebayo

E TUN LE WO:

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here