Ijoba Orun Ko Fee, Mi O Le Ya TATTOO – Oyita

Ijoba Orun Ko Fee, Mi O Le Ya TATTOO – Oyita

Osere Oyita ni alejo wa lori Miliki Express Pelu Ayinke ati Bimbo ti won si soro nipa imnua ati iwokuwo awon osere obirin ni nollywood, storyline awon ere agbelewo nollywood ati idi ti awon story won fi ma n jo ara won.

Lori eto, Ayinke bi Osere Oyita boya o le ya tatoo tabi lu eti, ahan tabi imu… Nkan ti Oyita so, e gbo ninu fidio

E TUN LE WO:

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here