Ko Si Eni To Ni Iru Awo Orin Mi Ni Nigeria- KOFFI

Ko Si Eni To Ni Iru Awo Orin Mi Ni Nigeria- KOFFI

Aderinposhonu Agba ni orileede Nigeria, Koffi Ayinde Idowu Nuel ti gbogbo wa mo si Koffi Tha Guru je adderinposhonu ti o ma n se efe ti o ni oro idoti ninu ti o si n ko gbogbo eni ti o ba gbo logbon. Koffi naa o gbeyin gege bi aderinposhonu, o ma n ko orin hiphop pelu ti o si man fi orisirisi efe sinu fidio orin won…

E TUN KA: IHA TI AWON OBI KO SI ISE MI- KENNY BLAQ

Koffi ni alejo ayinke ati bimbo lroi eti miliki express, won si soro nipa awon ere aderinposhonu kekeeke ti o n pe ni Muta ati Mutiu lori ero abanidore Instagram re ni @koffithaguru, bakanna won soro nipa awo orin won ti won sese se ti won si ti se tan lati gbe sita…..

E wo ke gbadun e…

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here