IHA TI AWON OBI KO SI ISE MI- KENNY BLAQ

IHA TI AWON OBI KO SI ISE MI- KENNY BLAQ

Kenny Blaq je aderinposhonu ti o je aayo gbogbo awon aderinposhonu ni Nigeria de bi wipe ko si ayeye tabi apeje ti won o ki n pe si lati wa mu won ni arada. Lai pe yi lo se show re ni eko hotel ti gbogbo aye si gbo ri yin fun ise takuntakun ti o se ni ojo naa. Lori Miliki express pelu Ayinke ati Busola ni Kenny Blaq ti je alejo wa ti o si soro nipa iha ti awon obi oun ko si ise aerinposhonu ti o un yan laayo…..

E TUN LE KA:

Bi Mo Se Ko Orin Ibadan Pelu Olamide- QDOT

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here