Eni Ti O Ba Rewa Ma Rewa Ti O Ba Rerin- Kenny Blaq

Eni Ti O Ba Rewa Ma Rewa Ti O Ba Rerin- Kenny Blaq

Kenny Blaq je aderinposhonu ti o n gba igboro kan ni owo yii. Gbogbo apeje ti o n shele ni nigeria ati oke okun ni ogbeni kenny blaq je aayo fun.

E TUN LE KA: Bi Mo Se Ko Orin Ibadan Pelu Olamide- QDOT

Lori eto Miliki Express, ogbeni Kenny Blaq ati Ayinke fi oro jomitoro nipa bi o ti bere ise aderinposhonu ati nipa kiko orin ninu aderinposhonu ti o n se.

E WO LOKE…

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here