Awa O Ki N Paro Ki A To Gbe Orin Tuntun Jade, Olamide Lo Sobe Lori Miliki Express

Awa O Ki N Paro Ki A To Gbe Orin Tuntun Jade, Olamide Lo Sobe Lori Miliki Express

Guest: -

Olorin Agbaye Olamide Ti Jade lati Soro wipe, Oun Kii Paro, tabi se “PR Stunt” kankan ki o to se Agbekale Orin Tuntun, Eyi ni Oro Ti Olamide So Leyin Igba Ti O Se Agbekale EP re tuntun Ti O Pe ni 999 EP.

E WO Ekunrere Oro Naa

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here